Nọ́ńbà 31:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: 2 “Gbẹ̀san+ lára àwọn ọmọ Mídíánì+ torí ohun tí wọ́n ṣe fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. Lẹ́yìn náà, a máa kó ọ jọ pẹ̀lú àwọn èèyàn rẹ.”*+
31 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: 2 “Gbẹ̀san+ lára àwọn ọmọ Mídíánì+ torí ohun tí wọ́n ṣe fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. Lẹ́yìn náà, a máa kó ọ jọ pẹ̀lú àwọn èèyàn rẹ.”*+