Nọ́ńbà 25:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Bí Ísírẹ́lì ṣe bẹ̀rẹ̀ sí í bá wọn jọ́sìn* Báálì Péórì+ nìyẹn, inú sì bí Jèhófà gidigidi sí Ísírẹ́lì. Nọ́ńbà 31:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ẹ wò ó! Àwọn ló tẹ̀ lé ọ̀rọ̀ Báláámù láti sún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì hùwà àìṣòótọ́+ sí Jèhófà nínú ọ̀rọ̀ Péórì,+ tí àjàkálẹ̀ àrùn fi kọ lu àpéjọ Jèhófà.+
3 Bí Ísírẹ́lì ṣe bẹ̀rẹ̀ sí í bá wọn jọ́sìn* Báálì Péórì+ nìyẹn, inú sì bí Jèhófà gidigidi sí Ísírẹ́lì.
16 Ẹ wò ó! Àwọn ló tẹ̀ lé ọ̀rọ̀ Báláámù láti sún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì hùwà àìṣòótọ́+ sí Jèhófà nínú ọ̀rọ̀ Péórì,+ tí àjàkálẹ̀ àrùn fi kọ lu àpéjọ Jèhófà.+