ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 25:17, 18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 “Ẹ lọ gbéjà ko àwọn ọmọ Mídíánì, kí ẹ sì ṣá wọn balẹ̀,+ 18 torí wọ́n ti ń dọ́gbọ́n gbéjà kò yín bí wọ́n ṣe fi ẹ̀tàn mú yín nínú ohun tó ṣẹlẹ̀ nínú ọ̀rọ̀ Péórì+ àti ọ̀rọ̀ Kọ́síbì ọmọ ìjòyè Mídíánì, arábìnrin wọn tí ẹ pa+ lọ́jọ́ tí àjàkálẹ̀ àrùn kọ lù yín torí ọ̀rọ̀ Péórì.”+

  • Diutarónómì 4:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 “Ẹ ti fi ojú ara yín rí ohun tí Jèhófà ṣe nínú ọ̀rọ̀ Báálì Péórì; gbogbo ọkùnrin tó tọ Báálì Péórì+ lẹ́yìn ni Jèhófà Ọlọ́run yín pa run kúrò láàárín yín.

  • Jóṣúà 22:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Ṣé ẹ̀ṣẹ̀ tí a dá ní Péórì kò tíì tó wa ni? A ò tíì wẹ ara wa mọ́ nínú rẹ̀ títí dòní, láìka ti àjàkálẹ̀ àrùn tó jà láàárín àpéjọ Jèhófà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́