Nọ́ńbà 27:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Mú Jóṣúà ọmọ Núnì, ọkùnrin tí ẹ̀mí wà nínú rẹ̀, kí o sì gbé ọwọ́ rẹ lé e.+ Diutarónómì 3:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Fa iṣẹ́ lé Jóṣúà lọ́wọ́,+ kí o fún un ní ìṣírí, kí o sì mú un lọ́kàn le, torí òun ló máa kó àwọn èèyàn yìí sọdá,+ òun ló sì máa mú kí wọ́n jogún ilẹ̀ tí wàá rí.’ Jóṣúà 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Mósè ìránṣẹ́ mi ti kú.+ Gbéra, kí o sọdá Jọ́dánì, ìwọ àti gbogbo èèyàn yìí, kí ẹ sì lọ sí ilẹ̀ tí mo fẹ́ fún wọn, ìyẹn àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+
18 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Mú Jóṣúà ọmọ Núnì, ọkùnrin tí ẹ̀mí wà nínú rẹ̀, kí o sì gbé ọwọ́ rẹ lé e.+
28 Fa iṣẹ́ lé Jóṣúà lọ́wọ́,+ kí o fún un ní ìṣírí, kí o sì mú un lọ́kàn le, torí òun ló máa kó àwọn èèyàn yìí sọdá,+ òun ló sì máa mú kí wọ́n jogún ilẹ̀ tí wàá rí.’
2 “Mósè ìránṣẹ́ mi ti kú.+ Gbéra, kí o sọdá Jọ́dánì, ìwọ àti gbogbo èèyàn yìí, kí ẹ sì lọ sí ilẹ̀ tí mo fẹ́ fún wọn, ìyẹn àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+