Sáàmù 81:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ká ní àwọn èèyàn mi lè fetí sí mi,+Ká ní Ísírẹ́lì lè rìn ní àwọn ọ̀nà mi!+