Diutarónómì 32:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ká sọ pé wọ́n gbọ́n ni!+ Wọn ì bá ro ọ̀rọ̀ yìí dáadáa.+ Kí wọ́n ro ibi tó máa já sí.+