-
Léfítíkù 26:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ẹ ó máa pakà títí di ìgbà tí ẹ máa kórè èso àjàrà, ẹ ó sì máa kórè èso àjàrà títí di ìgbà tí ẹ máa fúnrúgbìn; ẹ ó jẹun ní àjẹyó, ẹ ó sì máa gbé láìséwu ní ilẹ̀ yín.+
-