Jẹ́nẹ́sísì 13:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Lọ́ọ̀tì wá gbójú sókè, ó sì rí i pé gbogbo agbègbè Jọ́dánì+ lómi dáadáa, (kí Jèhófà tó pa Sódómù àti Gòmórà run), bí ọgbà Jèhófà,+ bí ilẹ̀ Íjíbítì, títí lọ dé Sóárì.+
10 Lọ́ọ̀tì wá gbójú sókè, ó sì rí i pé gbogbo agbègbè Jọ́dánì+ lómi dáadáa, (kí Jèhófà tó pa Sódómù àti Gòmórà run), bí ọgbà Jèhófà,+ bí ilẹ̀ Íjíbítì, títí lọ dé Sóárì.+