-
Diutarónómì 27:2, 3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ní ọjọ́ tí ẹ bá sọdá Jọ́dánì sí ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run yín fẹ́ fún yín, kí ẹ to àwọn òkúta ńláńlá jọ, kí ẹ sì rẹ́ ẹ.*+ 3 Kí ẹ wá kọ gbogbo ọ̀rọ̀ Òfin yìí sára wọn tí ẹ bá ti sọdá, kí ẹ lè wọ ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run yín fẹ́ fún yín, ilẹ̀ tí wàrà àti oyin ti ń ṣàn, bí Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá yín ṣe ṣèlérí fún yín gẹ́lẹ́.+
-