Ẹ́kísódù 16:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ilé Ísírẹ́lì pe oúnjẹ náà ní “mánà.”*+ Ó funfun bí irúgbìn kọriáńdà, ó sì dùn bí àkàrà olóyin pẹlẹbẹ. Sáàmù 78:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ó ń rọ̀jò mánà sílẹ̀ fún wọn láti jẹ;Ó fún wọn ní ọkà ọ̀run.+
31 Ilé Ísírẹ́lì pe oúnjẹ náà ní “mánà.”*+ Ó funfun bí irúgbìn kọriáńdà, ó sì dùn bí àkàrà olóyin pẹlẹbẹ.