Ẹ́kísódù 34:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó sọ pé: “Jèhófà, tí mo bá ti rí ojúure rẹ, jọ̀ọ́ Jèhófà, máa bá wa lọ kí o sì wà láàárín wa,+ bó tiẹ̀ jẹ́ pé alágídí* ni wá,+ kí o dárí àṣìṣe àti ẹ̀ṣẹ̀ wa jì,+ kí o sì mú wa bí ohun ìní rẹ.” Sáàmù 78:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Wọn ò ní dà bí àwọn baba ńlá wọn,Ìran alágídí àti ọlọ̀tẹ̀,+Ìran tí ọkàn wọn ń ṣe ségesège*+Tí ẹ̀mí wọn ò sì jẹ́ olóòótọ́ sí Ọlọ́run.
9 Ó sọ pé: “Jèhófà, tí mo bá ti rí ojúure rẹ, jọ̀ọ́ Jèhófà, máa bá wa lọ kí o sì wà láàárín wa,+ bó tiẹ̀ jẹ́ pé alágídí* ni wá,+ kí o dárí àṣìṣe àti ẹ̀ṣẹ̀ wa jì,+ kí o sì mú wa bí ohun ìní rẹ.”
8 Wọn ò ní dà bí àwọn baba ńlá wọn,Ìran alágídí àti ọlọ̀tẹ̀,+Ìran tí ọkàn wọn ń ṣe ségesège*+Tí ẹ̀mí wọn ò sì jẹ́ olóòótọ́ sí Ọlọ́run.