Léfítíkù 20:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 “‘Ẹ gbọ́dọ̀ pa ọkùnrin tàbí obìnrin èyíkéyìí tó jẹ́ abẹ́mìílò tàbí woṣẹ́woṣẹ́.*+ Kí àwọn èèyàn sọ wọ́n lókùúta pa. Ẹ̀jẹ̀ wọn wà lórí wọn.’” 1 Kíróníkà 10:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Bí Sọ́ọ̀lù ṣe kú nìyẹn nítorí ìwà àìṣòótọ́ tó hù sí Jèhófà torí pé kò ṣe ohun tí Jèhófà+ sọ àti pé ó lọ wádìí lọ́dọ̀ abẹ́mìílò+
27 “‘Ẹ gbọ́dọ̀ pa ọkùnrin tàbí obìnrin èyíkéyìí tó jẹ́ abẹ́mìílò tàbí woṣẹ́woṣẹ́.*+ Kí àwọn èèyàn sọ wọ́n lókùúta pa. Ẹ̀jẹ̀ wọn wà lórí wọn.’”
13 Bí Sọ́ọ̀lù ṣe kú nìyẹn nítorí ìwà àìṣòótọ́ tó hù sí Jèhófà torí pé kò ṣe ohun tí Jèhófà+ sọ àti pé ó lọ wádìí lọ́dọ̀ abẹ́mìílò+