Léfítíkù 26:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Tí mo bá run ibi* tí ẹ kó búrẹ́dì*+ yín jọ sí, obìnrin mẹ́wàá ni yóò yan búrẹ́dì yín nínú ààrò kan ṣoṣo, wọ́n á máa wọn búrẹ́dì fún yín;+ ẹ ó jẹ, àmọ́ ẹ ò ní yó.+
26 Tí mo bá run ibi* tí ẹ kó búrẹ́dì*+ yín jọ sí, obìnrin mẹ́wàá ni yóò yan búrẹ́dì yín nínú ààrò kan ṣoṣo, wọ́n á máa wọn búrẹ́dì fún yín;+ ẹ ó jẹ, àmọ́ ẹ ò ní yó.+