-
Diutarónómì 4:27, 28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Jèhófà máa tú yín ká sáàárín àwọn èèyàn,+ díẹ̀ nínú yín ló sì máa ṣẹ́ kù+ láàárín àwọn orílẹ̀-èdè tí Jèhófà máa lé yín lọ. 28 Àwọn ọlọ́run tí wọ́n fi igi àti òkúta ṣe lẹ máa sìn níbẹ̀, èyí tí àwọn èèyàn fi ọwọ́ ṣe,+ àwọn ọlọ́run tí kò lè ríran, tí kò lè gbọ́ràn, tí kò lè jẹun, tí kò sì lè gbóòórùn.
-