-
Jẹ́nẹ́sísì 38:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Lẹ́yìn náà, arákùnrin rẹ̀ jáde, òun ni wọ́n so òwú pupa mọ́ lọ́wọ́, wọ́n sì pe orúkọ rẹ̀ ní Síírà.+
-
-
1 Kíróníkà 2:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Àwọn ọmọ Síírà ni Símírì, Étánì, Hémánì, Kálíkólì àti Dárà. Gbogbo wọn jẹ́ márùn-ún.
-