-
Jóṣúà 18:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Wọ́n pààlà náà ní apá ìwọ̀ oòrùn, ó sì yí gba gúúsù láti ibi òkè tó dojú kọ Bẹti-hórónì lápá gúúsù; ó parí sí Kiriati-báálì, ìyẹn Kiriati-jéárímù,+ ìlú Júdà. Èyí ni apá ìwọ̀ oòrùn.
-
-
1 Sámúẹ́lì 7:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Nítorí náà, àwọn ọkùnrin Kiriati-jéárímù wá, wọ́n gbé Àpótí Jèhófà lọ sí ilé Ábínádábù+ tó wà lórí òkè, wọ́n sì ya Élíásárì ọmọ rẹ̀ sí mímọ́ láti máa ṣọ́ Àpótí Jèhófà.
-