ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 6:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Dáfídì àti gbogbo àwọn ọkùnrin tó wà pẹ̀lú rẹ̀ bá lọ sí Baale-júdà kí wọ́n lè gbé Àpótí Ọlọ́run tòótọ́+ wá láti ibẹ̀, iwájú rẹ̀ ni àwọn èèyàn ti ń ké pe orúkọ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun,+ ẹni tó ń jókòó lórí* àwọn kérúbù.+

  • 2 Sámúẹ́lì 6:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Nítorí náà, wọ́n gbé Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ láti ilé Ábínádábù tó wà lórí òkè, Áhíò sì ń rìn lọ níwájú Àpótí náà.

  • 1 Kíróníkà 13:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Torí náà, Dáfídì pe gbogbo Ísírẹ́lì jọ láti odò* Íjíbítì títí dé Lebo-hámátì,*+ kí wọ́n lè gbé Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ wá láti Kiriati-jéárímù.+

  • 1 Kíróníkà 13:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Àmọ́, wọ́n gbé Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ sórí kẹ̀kẹ́ tuntun,+ wọ́n gbé e wá láti ilé Ábínádábù. Úsà àti Áhíò sì ń darí kẹ̀kẹ́ náà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́