ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 12:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Ìwọ̀nyí ni àwọn ọba ilẹ̀ tí Jóṣúà àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣẹ́gun lápá ìwọ̀ oòrùn Jọ́dánì, láti Baali-gádì,+ ní Àfonífojì Lẹ́bánónì+ títí dé Òkè Hálákì,+ tó lọ dé Séírì,+ tí Jóṣúà wá fún àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì ní ilẹ̀ àwọn ọba náà pé kó di tiwọn, bí ìpín wọn,+

  • Jóṣúà 12:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 ọba Ẹ́gílónì, ọ̀kan; ọba Gésérì,+ ọ̀kan;

  • Jóṣúà 16:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Àmọ́ wọn ò lé àwọn ọmọ Kénáánì tó ń gbé ní Gésérì+ kúrò, àwọn ọmọ Kénáánì ṣì ń gbé láàárín Éfúrémù títí di òní yìí,+ wọ́n sì ń fipá kó wọn ṣiṣẹ́ àṣekára.+

  • Jóṣúà 21:20, 21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Wọ́n fi kèké pín àwọn ìlú fún àwọn ìdílé ọmọ Kóhátì yòókù nínú àwọn ọmọ Léfì látinú ìpín ẹ̀yà Éfúrémù. 21 Wọ́n fún wọn ní ìlú ààbò tí ẹni tó bá pààyàn máa sá lọ,+ ìyẹn Ṣékémù+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀ ní agbègbè olókè Éfúrémù, Gésérì+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀,

  • 1 Àwọn Ọba 9:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 (Fáráò ọba Íjíbítì ti wá gba Gésérì, ó dáná sun ún, ó sì pa àwọn ọmọ Kénáánì+ tó ń gbé ìlú náà. Nítorí náà, ó fi ṣe ẹ̀bùn ìdágbére* fún ọmọbìnrin rẹ̀,+ aya Sólómọ́nì.)

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́