Diutarónómì 3:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “Jáírì+ ọmọ Mánásè gba gbogbo agbègbè Ágóbù+ títí dé ààlà àwọn ará Géṣúrì àti àwọn ará Máákátì,+ ó sì sọ àwọn abúlé Báṣánì yẹn ní orúkọ ara rẹ̀, ìyẹn Hafotu-jáírì*+ títí di òní olónìí.
14 “Jáírì+ ọmọ Mánásè gba gbogbo agbègbè Ágóbù+ títí dé ààlà àwọn ará Géṣúrì àti àwọn ará Máákátì,+ ó sì sọ àwọn abúlé Báṣánì yẹn ní orúkọ ara rẹ̀, ìyẹn Hafotu-jáírì*+ títí di òní olónìí.