-
Nọ́ńbà 26:55Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
55 Àmọ́, kèké+ ni kí ẹ fi pín ilẹ̀ náà. Orúkọ ẹ̀yà àwọn bàbá wọn ni kí ẹ fi pín ogún fún wọn.
-
-
Ìṣe 13:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Lẹ́yìn tó pa orílẹ̀-èdè méje run ní ilẹ̀ Kénáánì, ó fi ilẹ̀ wọn ṣe ogún fún àwọn baba ńlá wa.+
-