-
Nọ́ńbà 34:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Mósè wá sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé: “Èyí ni ilẹ̀ tí ẹ máa fi kèké+ pín bí ohun ìní, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ gẹ́lẹ́ pé kí wọ́n fún ẹ̀yà mẹ́sàn-án àti ààbọ̀.
-
-
Jóṣúà 18:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ohun tí ẹ máa ṣe ni pé kí ẹ pín ilẹ̀ náà sí ọ̀nà méje, kí ẹ mú un wá sọ́dọ̀ mi níbí, màá sì ṣẹ́ kèké lé e+ níbí fún yín níwájú Jèhófà Ọlọ́run wa.
-