-
Diutarónómì 32:16, 17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Àwọn ẹ̀mí èṣù ni wọ́n rúbọ sí, kì í ṣe Ọlọ́run,+
Wọ́n ń rúbọ sí àwọn ọlọ́run tí wọn ò mọ̀,
Àwọn tó ṣẹ̀ṣẹ̀ dé lẹ́nu àìpẹ́ yìí,
Sí àwọn ọlọ́run tí àwọn baba ńlá yín ò mọ̀.
-