ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 40:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 “Ní ọjọ́ kìíní oṣù kìíní, kí o to àgọ́ ìjọsìn, àgọ́ ìpàdé náà.+

  • Jóṣúà 18:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Nígbà náà, gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé jọ sí Ṣílò,+ wọ́n sì to àgọ́ ìpàdé síbẹ̀,+ torí wọ́n ti ṣẹ́gun ilẹ̀ náà.+

  • 1 Sámúẹ́lì 1:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Lọ́dọọdún, ọkùnrin yẹn máa ń lọ láti ìlú rẹ̀ sí Ṣílò+ láti jọ́sìn,* kó sì rúbọ sí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun. Ibẹ̀ ni àwọn ọmọkùnrin Élì méjèèjì, Hófínì àti Fíníhásì+ ti ń ṣe iṣẹ́ àlùfáà fún Jèhófà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́