Rúùtù 2:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Náómì wá sọ fún ìyàwó ọmọ rẹ̀ pé: “Ìbùkún ni fún un látọ̀dọ̀ Jèhófà, ẹni tó ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí àwọn alààyè àti òkú.”+ Náómì ń bá ọ̀rọ̀ rẹ̀ lọ pé: “Mọ̀lẹ́bí wa ni ọkùnrin náà.+ Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùtúnrà* wa.”+ Rúùtù 4:21, 22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Sálímọ́nì bí Bóásì; Bóásì bí Óbédì; 22 Óbédì bí Jésè;+ Jésè sì bí Dáfídì.+ Mátíù 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ráhábù+ bí Bóásì fún Sálímọ́nì;Rúùtù bí Óbédì fún Bóásì;+Óbédì bí Jésè;+ Lúùkù 3:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Nǹkan bí ẹni ọgbọ̀n (30) ọdún+ ni Jésù+ nígbà tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀, bí wọ́n sì ṣe rò, ó jẹ́ ọmọJósẹ́fù,+ọmọ Hélì, Lúùkù 3:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 ọmọ Jésè,+ọmọ Óbédì,+ọmọ Bóásì,+ọmọ Sálímọ́nì,+ọmọ Náṣónì, + Yorùbá Publications (1987-2025) Jáde Wọlé Yorùbá Fi Ráńṣẹ́ Èyí tí mo fẹ́ràn jù Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania Àdéhùn Nípa Lílò Òfin Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ JW.ORG Wọlé Fi Ráńṣẹ́ Fi Ráńṣẹ́ Lórí Email
20 Náómì wá sọ fún ìyàwó ọmọ rẹ̀ pé: “Ìbùkún ni fún un látọ̀dọ̀ Jèhófà, ẹni tó ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí àwọn alààyè àti òkú.”+ Náómì ń bá ọ̀rọ̀ rẹ̀ lọ pé: “Mọ̀lẹ́bí wa ni ọkùnrin náà.+ Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùtúnrà* wa.”+
5 Ráhábù+ bí Bóásì fún Sálímọ́nì;Rúùtù bí Óbédì fún Bóásì;+Óbédì bí Jésè;+ Lúùkù 3:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Nǹkan bí ẹni ọgbọ̀n (30) ọdún+ ni Jésù+ nígbà tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀, bí wọ́n sì ṣe rò, ó jẹ́ ọmọJósẹ́fù,+ọmọ Hélì, Lúùkù 3:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 ọmọ Jésè,+ọmọ Óbédì,+ọmọ Bóásì,+ọmọ Sálímọ́nì,+ọmọ Náṣónì, + Yorùbá Publications (1987-2025) Jáde Wọlé Yorùbá Fi Ráńṣẹ́ Èyí tí mo fẹ́ràn jù Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania Àdéhùn Nípa Lílò Òfin Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ JW.ORG Wọlé Fi Ráńṣẹ́ Fi Ráńṣẹ́ Lórí Email
23 Nǹkan bí ẹni ọgbọ̀n (30) ọdún+ ni Jésù+ nígbà tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀, bí wọ́n sì ṣe rò, ó jẹ́ ọmọJósẹ́fù,+ọmọ Hélì, Lúùkù 3:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 ọmọ Jésè,+ọmọ Óbédì,+ọmọ Bóásì,+ọmọ Sálímọ́nì,+ọmọ Náṣónì, +