2 Sámúẹ́lì 7:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ní báyìí, sọ fún Dáfídì ìránṣẹ́ mi pé, ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Mo mú ọ láti ibi ìjẹko, pé kí o má da agbo ẹran mọ́,+ kí o lè wá di aṣáájú àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì.+ 1 Kíróníkà 2:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jésè bí àkọ́bí rẹ̀ Élíábù, ìkejì Ábínádábù,+ ìkẹta Ṣíméà,+ 1 Kíróníkà 2:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 ìkẹfà Ósémù àti ìkeje Dáfídì.+
8 Ní báyìí, sọ fún Dáfídì ìránṣẹ́ mi pé, ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: “Mo mú ọ láti ibi ìjẹko, pé kí o má da agbo ẹran mọ́,+ kí o lè wá di aṣáájú àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì.+