ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 10:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Mósè sọ fún Hóbábù ọmọ Réúẹ́lì*+ ọmọ ilẹ̀ Mídíánì, bàbá ìyàwó Mósè pé: “À ń lọ síbi tí Jèhófà sọ nípa rẹ̀ pé, ‘Èmi yóò fún yín.’+ Bá wa lọ,+ a ó sì tọ́jú rẹ dáadáa, torí Jèhófà ti ṣèlérí àwọn ohun rere fún Ísírẹ́lì.”+

  • Nọ́ńbà 10:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Tí o bá sì bá wa lọ,+ ó dájú pé ohun rere èyíkéyìí tí Jèhófà bá ṣe fún wa la máa ṣe fún ọ.”

  • Nọ́ńbà 24:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Nígbà tó rí àwọn Kénì,+ ó ń bá ọ̀rọ̀ rẹ̀ lọ lówelówe pé:

      “Ibùgbé rẹ ní ààbò, orí àpáta sì ni ilé rẹ fìkàlẹ̀ sí.

  • Àwọn Onídàájọ́ 1:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Àtọmọdọ́mọ àwọn Kénì,+ tó jẹ́ bàbá ìyàwó Mósè+ pẹ̀lú àwọn èèyàn Júdà wá láti ìlú ọlọ́pẹ+ sí aginjù Júdà, tó wà ní gúúsù Árádì.+ Wọ́n lọ síbẹ̀, wọ́n sì ń gbé láàárín àwọn èèyàn náà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́