ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àwọn Onídàájọ́ 3:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Èyí ni àwọn orílẹ̀-èdè tí Jèhófà fi sílẹ̀, láti dán gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wò, àwọn tí ogun kankan ò ṣẹlẹ̀ lójú wọn rí ní Kénáánì+

  • Àwọn Onídàájọ́ 3:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 àwọn alákòóso Filísínì+ márààrún àti gbogbo àwọn ọmọ Kénáánì, àwọn ọmọ Sídónì+ àti àwọn Hífì+ tó ń gbé Òkè Lẹ́bánónì+ láti Òkè Baali-hámónì títí dé Lebo-hámátì.*+

  • 1 Sámúẹ́lì 9:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 “Ní ìwòyí ọ̀la, màá rán ọkùnrin kan láti ilẹ̀ Bẹ́ńjámínì sí ọ.+ Kí o fòróró yàn án ṣe aṣáájú lórí àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì,+ yóò sì gba àwọn èèyàn mi lọ́wọ́ àwọn Filísínì. Nítorí mo ti rí ìpọ́njú àwọn èèyàn mi, igbe ẹkún wọn sì ti dé ọ̀dọ̀ mi.”+

  • 1 Sámúẹ́lì 14:52
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 52 Ogun tó le ni àwọn Filísínì dojú kọ nígbà ayé Sọ́ọ̀lù.+ Tí Sọ́ọ̀lù bá sì rí ọkùnrin èyíkéyìí tó lágbára tàbí tó láyà, á gbà á síṣẹ́ ogun.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́