1 Sámúẹ́lì 30:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Dáfídì wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà+ pé: “Ṣé kí n lépa àwọn jàǹdùkú* yìí? Ṣé màá lé wọn bá?” Ó sọ fún un pé: “Lépa wọn, torí ó dájú pé wàá lé wọn bá, wàá sì gba àwọn èèyàn rẹ pa dà.”+ Sáàmù 34:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ìṣòro* olódodo máa ń pọ̀,+Àmọ́ Jèhófà ń gbà á sílẹ̀ nínú gbogbo rẹ̀.+
8 Dáfídì wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà+ pé: “Ṣé kí n lépa àwọn jàǹdùkú* yìí? Ṣé màá lé wọn bá?” Ó sọ fún un pé: “Lépa wọn, torí ó dájú pé wàá lé wọn bá, wàá sì gba àwọn èèyàn rẹ pa dà.”+