Ẹ́kísódù 40:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Nígbà tí Mósè to àgọ́ ìjọsìn náà, ó fi àwọn ìtẹ́lẹ̀ oníhò rẹ̀+ sísàlẹ̀, ó to àwọn férémù,+ ó fi àwọn ọ̀pá gbọọrọ rẹ̀+ sí i, ó sì to àwọn òpó rẹ̀. Ẹ́kísódù 40:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Ìkùukùu* sì bẹ̀rẹ̀ sí í bo àgọ́ ìpàdé, ògo Jèhófà sì kún inú àgọ́ ìjọsìn náà.+
18 Nígbà tí Mósè to àgọ́ ìjọsìn náà, ó fi àwọn ìtẹ́lẹ̀ oníhò rẹ̀+ sísàlẹ̀, ó to àwọn férémù,+ ó fi àwọn ọ̀pá gbọọrọ rẹ̀+ sí i, ó sì to àwọn òpó rẹ̀.