Diutarónómì 7:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ó máa fi àwọn ọba wọn lé ọ lọ́wọ́,+ o sì máa pa orúkọ wọn run kúrò lábẹ́ ọ̀run.+ Kò sẹ́ni tó máa dìde sí ọ+ títí o fi máa pa wọ́n run tán.+ 2 Sámúẹ́lì 8:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ó fi àwọn àwùjọ ọmọ ogun àdádó sí Édómù. Gbogbo Édómù ni ó fi àwọn àwùjọ ọmọ ogun àdádó sí, gbogbo àwọn ọmọ Édómù sì di ìránṣẹ́ Dáfídì.+ Jèhófà sì ń jẹ́ kí Dáfídì ṣẹ́gun* ní ibikíbi tó bá lọ.+
24 Ó máa fi àwọn ọba wọn lé ọ lọ́wọ́,+ o sì máa pa orúkọ wọn run kúrò lábẹ́ ọ̀run.+ Kò sẹ́ni tó máa dìde sí ọ+ títí o fi máa pa wọ́n run tán.+
14 Ó fi àwọn àwùjọ ọmọ ogun àdádó sí Édómù. Gbogbo Édómù ni ó fi àwọn àwùjọ ọmọ ogun àdádó sí, gbogbo àwọn ọmọ Édómù sì di ìránṣẹ́ Dáfídì.+ Jèhófà sì ń jẹ́ kí Dáfídì ṣẹ́gun* ní ibikíbi tó bá lọ.+