1 Sámúẹ́lì 26:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ìgbà náà ni Dáfídì sọ fún Áhímélékì ọmọ Hétì+ àti Ábíṣáì+ ọmọ Seruáyà,+ ẹ̀gbọ́n Jóábù pé: “Ta ló máa tẹ̀ lé mi lọ sí ibùdó lọ́dọ̀ Sọ́ọ̀lù?” Ábíṣáì fèsì pé: “Màá tẹ̀ lé ọ.” 2 Sámúẹ́lì 2:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Àwọn ọmọ Seruáyà+ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta wà níbẹ̀, Jóábù,+ Ábíṣáì+ àti Ásáhélì;+ ẹsẹ̀ Ásáhélì sì yá nílẹ̀ bíi ti àgbọ̀nrín inú pápá. 2 Sámúẹ́lì 23:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ábíṣáì+ ẹ̀gbọ́n Jóábù ọmọ Seruáyà+ ni olórí àwọn mẹ́ta míì; ó fi ọ̀kọ̀ rẹ̀ pa ọgọ́rùn-ún mẹ́ta (300), òun náà sì lórúkọ bí àwọn mẹ́ta àkọ́kọ́.+ 1 Kíróníkà 2:15, 16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 ìkẹfà Ósémù àti ìkeje Dáfídì.+ 16 Àwọn arábìnrin wọn ni Seruáyà àti Ábígẹ́lì.+ Àwọn ọmọ Seruáyà ni Ábíṣáì,+ Jóábù+ àti Ásáhélì,+ àwọn mẹ́ta.
6 Ìgbà náà ni Dáfídì sọ fún Áhímélékì ọmọ Hétì+ àti Ábíṣáì+ ọmọ Seruáyà,+ ẹ̀gbọ́n Jóábù pé: “Ta ló máa tẹ̀ lé mi lọ sí ibùdó lọ́dọ̀ Sọ́ọ̀lù?” Ábíṣáì fèsì pé: “Màá tẹ̀ lé ọ.”
18 Àwọn ọmọ Seruáyà+ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta wà níbẹ̀, Jóábù,+ Ábíṣáì+ àti Ásáhélì;+ ẹsẹ̀ Ásáhélì sì yá nílẹ̀ bíi ti àgbọ̀nrín inú pápá.
18 Ábíṣáì+ ẹ̀gbọ́n Jóábù ọmọ Seruáyà+ ni olórí àwọn mẹ́ta míì; ó fi ọ̀kọ̀ rẹ̀ pa ọgọ́rùn-ún mẹ́ta (300), òun náà sì lórúkọ bí àwọn mẹ́ta àkọ́kọ́.+
15 ìkẹfà Ósémù àti ìkeje Dáfídì.+ 16 Àwọn arábìnrin wọn ni Seruáyà àti Ábígẹ́lì.+ Àwọn ọmọ Seruáyà ni Ábíṣáì,+ Jóábù+ àti Ásáhélì,+ àwọn mẹ́ta.