-
Òwe 3:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Aláyọ̀ ni ẹni tó wá ọgbọ́n rí+
Àti ẹni tó ní òye;
-
Òwe 3:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Ẹ̀mí gígùn wà ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀;
Ọrọ̀ àti ògo sì wà ní ọwọ́ òsì rẹ̀.
-
-
-