31 “Màá pààlà fún yín láti Òkun Pupa dé òkun àwọn Filísínì àti láti aginjù dé Odò;*+ torí màá mú kí ọwọ́ yín tẹ àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà, ẹ ó sì lé wọn kúrò níwájú yín.+
13 Àmọ́ wòlíì kan wá bá Áhábù+ ọba Ísírẹ́lì, ó sọ fún un pé: “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Ṣé o rí gbogbo èèyàn rẹpẹtẹ yìí? Màá fi wọ́n lé ọ lọ́wọ́ lónìí, wàá sì mọ̀ pé èmi ni Jèhófà.’”+