ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kíróníkà 9:10, 11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Yàtọ̀ síyẹn, àwọn ìránṣẹ́ Hírámù àti àwọn ìránṣẹ́ Sólómọ́nì tí wọ́n kó wúrà wá láti Ófírì+ tún kó àwọn gẹdú igi álígọ́mù àti àwọn òkúta iyebíye wá.+ 11 Ọba fi àwọn gẹdú igi álígọ́mù náà ṣe àtẹ̀gùn sí ilé Jèhófà+ àti sí ilé* ọba,+ títí kan àwọn háàpù àti àwọn ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín fún àwọn akọrin.+ A kò rí irú àwọn nǹkan yìí rí ní ilẹ̀ Júdà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́