ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 16:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Ómírì ń ṣe ohun tó burú lójú Jèhófà nígbà gbogbo, tiẹ̀ tún burú ju ti gbogbo àwọn tó ṣáájú rẹ̀.+

  • 1 Àwọn Ọba 21:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Ó dájú pé kò sí ẹni tó dà bí Áhábù,+ ẹni tó ti pinnu* láti máa ṣe ohun tó burú lójú Jèhófà, ẹni tí Jésíbẹ́lì+ ìyàwó rẹ̀ ń tì gbọ̀n-ọ́n gbọ̀n-ọ́n.

  • 2 Àwọn Ọba 3:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Jèhórámù+ ọmọ Áhábù di ọba lórí Ísírẹ́lì ní Samáríà ní ọdún kejìdínlógún Jèhóṣáfátì ọba Júdà, ọdún méjìlá (12) ló sì fi ṣàkóso. 2 Ó ń ṣe ohun tó burú lójú Jèhófà, àmọ́ kò ṣe tó ohun tí bàbá àti ìyá rẹ̀ ṣe, nítorí ó mú ọwọ̀n òrìṣà Báálì tí bàbá rẹ̀ ṣe kúrò.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́