Ẹ́kísódù 20:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 O ò gbọ́dọ̀ ní ọlọ́run kankan yàtọ̀ sí mi.*+ Ẹ́kísódù 34:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 O ò gbọ́dọ̀ forí balẹ̀ fún ọlọ́run míì,+ torí Jèhófà máa ń fẹ́* kí a jọ́sìn òun nìkan.* Àní, ó jẹ́ Ọlọ́run tó fẹ́ kí a máa sin òun nìkan.+
14 O ò gbọ́dọ̀ forí balẹ̀ fún ọlọ́run míì,+ torí Jèhófà máa ń fẹ́* kí a jọ́sìn òun nìkan.* Àní, ó jẹ́ Ọlọ́run tó fẹ́ kí a máa sin òun nìkan.+