ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 19:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Torí náà, ó kúrò níbẹ̀, ó sì rí Èlíṣà ọmọ Ṣáfátì níbi tó ti ń fi àwọn akọ màlúù tí wọ́n dì ní méjì-méjì sọ́nà méjìlá (12) túlẹ̀ níwájú rẹ̀, ó sì wà pẹ̀lú ìkejìlá. Nítorí náà, Èlíjà lọ sọ́dọ̀ rẹ̀, ó sì ju ẹ̀wù oyè rẹ̀+ sí i lọ́rùn.

  • 2 Àwọn Ọba 1:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Torí náà, wọ́n sọ fún un pé: “Ọkùnrin náà wọ aṣọ onírun,+ ó sì de àmùrè awọ mọ́ ìbàdí rẹ̀.”+ Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, ó sọ pé: “Èlíjà ará Tíṣíbè ni.”

  • Sekaráyà 13:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 “Ní ọjọ́ yẹn, ojú yóò ti àwọn wòlíì nítorí ìran tí kálukú wọn ń rí nígbà tó ń sọ àsọtẹ́lẹ̀; wọn ò sì ní wọ aṣọ onírun+ mọ́ láti tan àwọn èèyàn jẹ.

  • Mátíù 3:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Jòhánù wọ aṣọ tí wọ́n fi irun ràkúnmí ṣe, ó sì de àmùrè tí wọ́n fi awọ ṣe mọ́ ìbàdí rẹ̀.+ Eéṣú àti oyin ìgàn ni oúnjẹ rẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́