ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 12:13, 14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Kí ẹ rí i pé ẹ ò rú àwọn ẹbọ sísun yín níbòmíì tí ẹ bá rí.+ 14 Ibi tí Jèhófà yàn nínú ọ̀kan lára àwọn ilẹ̀ tó jẹ́ ti ẹ̀yà yín nìkan ni kí ẹ ti rú àwọn ẹbọ sísun yín, ibẹ̀ sì ni kí ẹ ti ṣe gbogbo ohun tí mò ń pa láṣẹ fún yín.+

  • 1 Àwọn Ọba 22:41
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 41 Jèhóṣáfátì+ ọmọ Ásà di ọba lórí Júdà ní ọdún kẹrin Áhábù ọba Ísírẹ́lì.

  • 1 Àwọn Ọba 22:43
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 43 Ó ń rìn ní gbogbo ọ̀nà Ásà+ bàbá rẹ̀. Kò yà kúrò nínú rẹ̀, ó sì ṣe ohun tí ó tọ́ lójú Jèhófà.+ Àmọ́ kò mú àwọn ibi gíga kúrò, àwọn èèyàn náà ṣì ń rúbọ, wọ́n sì ń mú ẹbọ rú èéfín ní àwọn ibi gíga.+

  • 2 Àwọn Ọba 14:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Ní ọdún kejì Jèhóáṣì+ ọmọ Jèhóáhásì ọba Ísírẹ́lì, Amasááyà ọmọ Jèhóáṣì ọba Júdà di ọba.

  • 2 Àwọn Ọba 14:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Àmọ́ kò mú àwọn ibi gíga kúrò,+ àwọn èèyàn náà ṣì ń rúbọ, wọ́n sì ń mú ẹbọ rú èéfín ní àwọn ibi gíga.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́