ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 21:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 ‘Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí: “Wò ó, màá jẹ́ kí àwọn ohun ìjà tó wà ní ọwọ́ yín dojú kọ yín,* àwọn ohun tí ẹ fi ń bá ọba Bábílónì jà+ pẹ̀lú àwọn ará Kálídíà tí wọ́n dó tì yín lẹ́yìn odi. Màá sì kó wọn jọ sí àárín ìlú yìí.

  • Jeremáyà 39:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Ní ọdún kọkànlá Sedekáyà, ní oṣù kẹrin, ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù náà, wọ́n fọ́ ògiri ìlú náà wọlé.+

  • Jeremáyà 39:4-7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Nígbà tí Sedekáyà ọba Júdà àti gbogbo ọmọ ogun rí wọn, wọ́n fẹsẹ̀ fẹ,+ wọ́n gba ọ̀nà ọgbà ọba jáde kúrò nínú ìlú náà lóru, wọ́n gba ẹnubodè tó wà láàárín ògiri oníbejì kọjá, wọ́n sì gba ọ̀nà Árábà jáde.+ 5 Àmọ́ àwọn ọmọ ogun Kálídíà lé wọn, wọ́n sì bá Sedekáyà ní aṣálẹ̀ tó wà ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ Jẹ́ríkò.+ Wọ́n gbá a mú, wọ́n sì mú un wá sọ́dọ̀ Nebukadinésárì* ọba Bábílónì ní Ríbúlà+ ní ilẹ̀ Hámátì,+ ibẹ̀ ló sì ti dá a lẹ́jọ́. 6 Ọba Bábílónì ní kí wọ́n pa àwọn ọmọ Sedekáyà níṣojú rẹ̀ ní Ríbúlà, ọba Bábílónì sì ní kí wọ́n pa gbogbo èèyàn pàtàkì Júdà.+ 7 Lẹ́yìn náà, ó fọ́ ojú Sedekáyà, ó sì fi ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀ bàbà dè é kó lè mú un wá sí Bábílónì.+

  • Ìsíkíẹ́lì 33:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Nígbà tó yá, ní ọjọ́ karùn-ún, oṣù kẹwàá, ọdún kejìlá tí a ti wà ní ìgbèkùn, ọkùnrin kan tó sá àsálà kúrò ní Jerúsálẹ́mù wá bá mi,+ ó sì sọ pé: “Wọ́n ti pa ìlú náà run!”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́