Jóṣúà 15:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wọ́n pààlà náà látorí òkè dé ibi ìsun omi Néfítóà,+ ó sì lọ dé àwọn ìlú Òkè Éfúrónì; wọ́n tún pààlà dé Báálà, ìyẹn Kiriati-jéárímù.+ Jóṣúà 15:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ààlà náà lápá ìwọ̀ oòrùn ni Òkun Ńlá*+ àti èbúté rẹ̀. Èyí ni ààlà àwọn àtọmọdọ́mọ Júdà ní ìdílé-ìdílé yí ká. 1 Kíróníkà 13:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Torí náà, Dáfídì pe gbogbo Ísírẹ́lì jọ láti odò* Íjíbítì títí dé Lebo-hámátì,*+ kí wọ́n lè gbé Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ wá láti Kiriati-jéárímù.+
9 Wọ́n pààlà náà látorí òkè dé ibi ìsun omi Néfítóà,+ ó sì lọ dé àwọn ìlú Òkè Éfúrónì; wọ́n tún pààlà dé Báálà, ìyẹn Kiriati-jéárímù.+
12 Ààlà náà lápá ìwọ̀ oòrùn ni Òkun Ńlá*+ àti èbúté rẹ̀. Èyí ni ààlà àwọn àtọmọdọ́mọ Júdà ní ìdílé-ìdílé yí ká.
5 Torí náà, Dáfídì pe gbogbo Ísírẹ́lì jọ láti odò* Íjíbítì títí dé Lebo-hámátì,*+ kí wọ́n lè gbé Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ wá láti Kiriati-jéárímù.+