ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 9:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Jóṣúà bá wọn ṣàdéhùn àlàáfíà,+ ó sì bá wọn dá májẹ̀mú pé òun máa dá ẹ̀mí wọn sí, ohun tí àwọn ìjòyè àpéjọ náà sì búra fún wọn nìyẹn.+

  • Jóṣúà 9:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì bá gbéra, wọ́n sì dé àwọn ìlú wọn ní ọjọ́ kẹta; àwọn ìlú wọn ni Gíbíónì,+ Kéfírà, Béérótì àti Kiriati-jéárímù.+

  • Jóṣúà 21:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Bí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe fi kèké pín àwọn ìlú yìí àtàwọn ibi ìjẹko wọn fún àwọn ọmọ Léfì nìyẹn, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ nípasẹ̀ Mósè.+

  • Jóṣúà 21:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Látinú ìpín ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì: Gíbíónì+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, Gébà pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀,+

  • 1 Kíróníkà 21:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Àgọ́ ìjọsìn Jèhófà tí Mósè ṣe ní aginjù àti pẹpẹ ẹbọ sísun ṣì wà ní ibi gíga Gíbíónì+ ní àkókò yẹn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́