1 Kíróníkà 10:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Bí Sọ́ọ̀lù ṣe kú nìyẹn nítorí ìwà àìṣòótọ́ tó hù sí Jèhófà torí pé kò ṣe ohun tí Jèhófà+ sọ àti pé ó lọ wádìí lọ́dọ̀ abẹ́mìílò+
13 Bí Sọ́ọ̀lù ṣe kú nìyẹn nítorí ìwà àìṣòótọ́ tó hù sí Jèhófà torí pé kò ṣe ohun tí Jèhófà+ sọ àti pé ó lọ wádìí lọ́dọ̀ abẹ́mìílò+