2 Sámúẹ́lì 3:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Bí Jóábù àti Ábíṣáì+ ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ṣe pa Ábínérì+ nítorí pé ó pa Ásáhélì àbúrò wọn ní Gíbíónì lójú ogun+ nìyẹn.
30 Bí Jóábù àti Ábíṣáì+ ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ṣe pa Ábínérì+ nítorí pé ó pa Ásáhélì àbúrò wọn ní Gíbíónì lójú ogun+ nìyẹn.