ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kíróníkà 27:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Iye àwọn ọmọ Ísírẹ́lì nìyí, àwọn olórí nínú àwọn agbo ilé, àwọn olórí ẹgbẹẹgbẹ̀rún àti ti ọgọ́rọ̀ọ̀rún+ àti àwọn aláṣẹ wọn tó ń ṣe ìránṣẹ́ fún ọba+ nínú gbogbo ọ̀rọ̀ tó jẹ mọ́ àwọn àwùjọ tó ń wọlé àti àwọn tó ń jáde ní oṣooṣù ní gbogbo oṣù tó wà nínú ọdún; ẹgbẹ̀rún mẹ́rìnlélógún (24,000) ló sì wà nínú àwùjọ kọ̀ọ̀kan.

  • 1 Kíróníkà 27:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Olórí àwùjọ kẹfà fún oṣù kẹfà ni Írà+ ọmọ Íkéṣì ará Tékóà,+ ẹgbẹ̀rún mẹ́rìnlélógún (24,000) ló sì wà nínú àwùjọ rẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́