2 Kíróníkà 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nígbà náà, Sólómọ́nì bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ ilé Jèhófà+ sí Jerúsálẹ́mù lórí Òkè Moráyà,+ níbi tí Jèhófà ti fara han Dáfídì bàbá rẹ̀,+ ibẹ̀ ni Dáfídì ṣètò sílẹ̀ ní ibi ìpakà Ọ́nánì+ ará Jébúsì.
3 Nígbà náà, Sólómọ́nì bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ ilé Jèhófà+ sí Jerúsálẹ́mù lórí Òkè Moráyà,+ níbi tí Jèhófà ti fara han Dáfídì bàbá rẹ̀,+ ibẹ̀ ni Dáfídì ṣètò sílẹ̀ ní ibi ìpakà Ọ́nánì+ ará Jébúsì.