2 Sámúẹ́lì 7:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 ọba sọ fún wòlíì Nátánì+ pé: “Mò ń gbé inú ilé tí wọ́n fi igi kédárì kọ́+ nígbà tí Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ wà láàárín àwọn aṣọ àgọ́.”+ 2 Sámúẹ́lì 12:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Nítorí náà, Jèhófà rán Nátánì+ sí Dáfídì. Ó wọlé wá bá a,+ ó sì sọ pé: “Àwọn ọkùnrin méjì wà nínú ìlú kan, ọ̀kan jẹ́ ọlọ́rọ̀, èkejì sì jẹ́ aláìní. 1 Àwọn Ọba 1:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àmọ́ àlùfáà Sádókù,+ Bẹnáyà+ ọmọ Jèhóádà, wòlíì Nátánì,+ Ṣíméì,+ Réì àti àwọn akíkanjú jagunjagun Dáfídì+ kò ti Ádóníjà lẹ́yìn. 1 Kíróníkà 29:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ní ti ìtàn Ọba Dáfídì láti ìbẹ̀rẹ̀ dé òpin, ó wà lákọsílẹ̀ nínú àwọn ọ̀rọ̀ Sámúẹ́lì aríran àti ti wòlíì Nátánì+ àti ti Gádì+ olùríran
2 ọba sọ fún wòlíì Nátánì+ pé: “Mò ń gbé inú ilé tí wọ́n fi igi kédárì kọ́+ nígbà tí Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ wà láàárín àwọn aṣọ àgọ́.”+
12 Nítorí náà, Jèhófà rán Nátánì+ sí Dáfídì. Ó wọlé wá bá a,+ ó sì sọ pé: “Àwọn ọkùnrin méjì wà nínú ìlú kan, ọ̀kan jẹ́ ọlọ́rọ̀, èkejì sì jẹ́ aláìní.
8 Àmọ́ àlùfáà Sádókù,+ Bẹnáyà+ ọmọ Jèhóádà, wòlíì Nátánì,+ Ṣíméì,+ Réì àti àwọn akíkanjú jagunjagun Dáfídì+ kò ti Ádóníjà lẹ́yìn.
29 Ní ti ìtàn Ọba Dáfídì láti ìbẹ̀rẹ̀ dé òpin, ó wà lákọsílẹ̀ nínú àwọn ọ̀rọ̀ Sámúẹ́lì aríran àti ti wòlíì Nátánì+ àti ti Gádì+ olùríran