1 Àwọn Ọba 10:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ọ̀wọ́ ọkọ̀ òkun tí Hírámù fi kó wúrà láti Ófírì+ tún kó àwọn gẹdú igi álígọ́mù+ tó pọ̀ gan-an wá àti àwọn òkúta iyebíye.+
11 Ọ̀wọ́ ọkọ̀ òkun tí Hírámù fi kó wúrà láti Ófírì+ tún kó àwọn gẹdú igi álígọ́mù+ tó pọ̀ gan-an wá àti àwọn òkúta iyebíye.+