-
Ẹ́kísódù 14:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Nígbà tí Fáráò ń sún mọ́ tòsí, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wòkè, wọ́n sì rí i pé àwọn ará Íjíbítì ń lépa wọn. Ẹ̀rù wá bẹ̀rẹ̀ sí í ba àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í ké pe Jèhófà.+
-
-
2 Kíróníkà 13:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Nígbà tí àwọn èèyàn Júdà bojú wẹ̀yìn, wọ́n rí i pé ogun ń bọ̀ níwájú, ogun ń bọ̀ lẹ́yìn. Torí náà, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í ké pe Jèhófà,+ àwọn àlùfáà sì ń fun kàkàkí kíkankíkan.
-