ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àwọn Onídàájọ́ 11:23, 24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 “‘Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì ló lé àwọn Ámórì kúrò níwájú Ísírẹ́lì èèyàn rẹ̀,+ ṣé o wá fẹ́ lé wọn kúrò ni? 24 Ṣebí ohunkóhun tí Kémóṣì+ ọlọ́run rẹ bá fún ọ pé kí o gbà lo máa ń gbà? Torí náà gbogbo àwọn tí Jèhófà Ọlọ́run wa bá lé kúrò níwájú wa la máa lé kúrò.+

  • Sáàmù 83:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Wò ó! àwọn ọ̀tá rẹ wà nínú rúkèrúdò;+

      Àwọn tó kórìíra rẹ ń hùwà ìgbéraga.*

  • Sáàmù 83:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Wọ́n sọ pé: “Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a pa wọ́n run kí wọ́n má ṣe jẹ́ orílẹ̀-èdè mọ́,+

      Kí a má sì rántí orúkọ Ísírẹ́lì mọ́.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́