Sáàmù 2:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Kí nìdí tí àwọn orílẹ̀-èdè fi ń ṣe awuyewuyeTí àwọn èèyàn sì ń sọ ohun asán lẹ́nu wúyẹ́wúyẹ́?*+ 2 Àwọn ọba ayé dúróÀwọn aláṣẹ sì kóra jọ*+Láti dojú kọ Jèhófà àti ẹni àmì òróró* rẹ̀.+
2 Kí nìdí tí àwọn orílẹ̀-èdè fi ń ṣe awuyewuyeTí àwọn èèyàn sì ń sọ ohun asán lẹ́nu wúyẹ́wúyẹ́?*+ 2 Àwọn ọba ayé dúróÀwọn aláṣẹ sì kóra jọ*+Láti dojú kọ Jèhófà àti ẹni àmì òróró* rẹ̀.+